Past Questions PDF
DOWNLOAD PAST QUESTIONS PDF
Download Now×

YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM FOR JSS 2

Todi4 min read

Complete Lesson Plan for Nigerian Schools – All Subjects and Classes | Savina Academy

YORUBA STUDIES LESSON PLAN FOR SECOND TERM -JSS 2

Week 

(Oṣe)

10 (Kẹwàá)
Date 

(Deeti)

March 11th to 15th, 2024 
Class 

(Kíláàsì)

JSS 2
Subject 

(Isẹ)

YORUBA
Period 

(Akoko)

4th
Duration 

(Iṣẹju)

40 minutes per period 

(Ogoji Iṣẹju)

Resources

(Iwe Itọkasi)

S.Y Adewoyin (New Edition, 2020) Simplified Yoruba L1 for JSS by Corpromutt Publishers.

M.K Gbadamosi (1st Edition, 2008) Asa ati Girama Yoruba by God’s Mercy Publishers

Instructional materials

(Irinṣẹ Ikọni) 

Lilo ate ti o n toka si orisii Ere Idaraya nile Yoruba 

Lilo fọnran to n safihan awon Ere Idaraya   

Theme 

(Akọle)

Ere Idaraya
Day 1 

(Ọjọ Kin-in-ni)

11th March 20244th period
Topic 

(Akọle)

Ere Idaraya 
Learning Objectives

(Erongba Idanilekoo) 

Lopin idanilẹkọọ awọn akẹkọọ gbọdọ le:

  1. kọ orin idaraya ni akọ-gbadun
  2. kọ orin idaraya lati fi ṣe ere
  3. kọ orin idaraya lati fi ṣe ere po pẹlu ẹlẹgbẹ wọn 
Key Vocabulary Words

(Ede Iperi) 

  • Egbe 
  • Lile
  • Ọgba
  • Ere osupa 
Previous Knowledge

(Imọ Atẹyinwa)

Awon akekoo ti imo nipa ere sise 
Content (Akoonu isẹ)Oriki Ere Idaraya 

Orisii Ere Idaraya   

Strategies/ Activities (Agbekalẹ)Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́.

Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo.

Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo.

Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko.

Classwork

(Iṣẹ ṣiṣe)

Ko orin eremode ti oluko ko 
Conclusion

(Igunlẹ) 

Olukọ salaye Ẹkọ lori Ere Idarayạ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati se afihan ere idaraya.
Assignment 

(Ise Amurele/ Asetilewa)

Ko orin Ere Idaraya miiran yato si ti oluko 

 

Day 2

(Ọjọ Keji)

14th March 20247th period 
Topic

(Akọle) 

Ere Idaraya
Learning Objectives

(Erongba Idanilẹkọọ) 

Lopin idanilẹkọọ awọn akẹkọọ gbọdọ le:

  1. kọ orin idaraya ni akọ-gbadun
  2. kọ orin idaraya lati fi ṣe ere
  3. kọ orin idaraya lati fi ṣe ere po pẹlu ẹlẹgbẹ wọn 
Key Vocabulary Words 

(Ede Iperi)

  • Egbe 
  • Lile
  • Ọgba
  • Ere osupa 
Previous Knowledge 

(Imọ Atẹyinwa)

Awon akekoo ti ni imo nipa orin ere idaraya
Content 

Akoonu Iṣẹ)

Oriki Ere Idaraya 

Orisii Ere Idaraya 

Strategies/ Activities 

(Agbekalẹ)

Step 1: Olùkọ́ se àfihàn àkólé iṣẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́.

Step 2: Oluko sa alaye akole ise fun awon akekoo.

Step 3: Oluko ko ise si oju patako fun awon akekoo.

Step 4: Awon akekoo ko ise naa tele oluko. 

Classwork

(Iṣẹ ṣiṣe)

Ko orin ere idaraya kan ti o mo pelu itumo ni ede Geesi 
Conclusion

(Igunlẹ)

Olukọ salaye Ẹkọ lori Ere Idarayạ ni ṣoki, lẹyin naa ni pipin awọn akẹkọọ si ọwọọwọ lati se afihan ere idaraya. 
Assignment 

(Ise Amurele/ Asetilewa)

Daruko orin ere idaraya meta ki o si salaye igba ati akoko ere naa.
Weekly quiz  
HODs. Comments and Endorsement

 

ERE IDARAYA

Ere idaraya ni ere ti awon omode tabi agbalagba maa n se lati je ki ara won ji pepe. Ni ale ni igba osupa ni awon omode maa n sere ti won idi niyi ti a fi n pe ni ere osupa. Apeere iru ere bee ni bojuboju, ekun meran,  ojo n ro, ta lo wa ninu ogba naa abbl.

 

EKUN MERAN

LILE (CALL)EGBE (RESPONSE)
Ekun meran (The leopard stalks the goat)Mee 
O tori bogbo (It searches the forest)Mee 
O torun bogba (It searches the bush)Mee 
O fe mu un (It wants to capture it)Mee 
Ko ma le ri mu (No you cant capture it)Mee 
Oju Ekun n pon (The leopard’s eyes are red)Mee 
Iru Ekun n le (the leopard’s tail stands on end)Mee 

 

 READ ALSO: JSS2 French Examination Question-3rd Term

OJO N RO

Ojo n roIt is raining
Sere ninu ilePlay inside the house
Ma wo inu ojoDon’t enter the rain
Ki aso re So that your cloth
Ko ma ba tutuWould not get wet
Ki otutuSo that cold
Ko ma ba mu oWould not catch you

 

TA LO WA NINU OGBA NAA

Ta lo wa ninu ogba naaWho’s in the garden/yard
Omo kekere kan niOne small kid
Se kin wa woCan I come and see her?
Mo wa wo No, don’t come and look
Tele mi kaloCome here and follow me

 

You can share this post

No comments yet. Be the first to share your thoughts.

Join the conversation

Your email address will not be published. Keep the discussion kind and on topic.

×WhatsApp Channel
JOIN OUR WHATSAPP CHANNEL
Join Now
Scroll to Top